OS World1

Ajaga (Burden) – Ope Gold

Ajaga (Burden)

Ope Gold

The song AJAGA is an inspired prayer song… it’s a revelation that is full of positive assurance.
Yes we can have a burden but surely it can be lifted off our shoulder and we will be free

Listen and Download here

https://osworld1.com/wp-content/uploads/2021/04/AJAGA.mp3?_=1

DOWNLOAD NOW mp3

Listen on audiomack

 

 

Sound Lyrics

Chorus

Ajaga gbo
Ajaga bo
Lorun mi o moti lo

Stanza 1

Opo lo n fokansin laye sugbon ounje iponju la fi n bowon
Awon to ye ko tara wa sin lohun won belu egan lu wa
İja ta maa ja ka to ga la n pe lajaga
Ajaga o ni se pelu owo nini
İkorita kan wa ti n doju towo lowo olowo
Ajaga ni n mekun asuunda wa ti n gbomi loju eni
Ohun to wu ko je ajaga re lo ni o o maa ha

Stanza 2

İwo eni ti a pon loju ti a n gba kiri
Olorun o ri bi eniyan laye tujuka o o maa se
Awon to ti pa o ti laye won pada bo wa ba o
Tori ojo ogo to su yi o…o maa ro sori i re
İja re ti dopin ogun si ti tan an an an

(İnterlude)

Bridge

Call:moti bo moti yege o
Resp: moti bo moti yege
Call:  i am free oo mo ti bo o
Resp: motibo motiyege

Call: lowo ogun to ko mini papa mora o moti bo
Resp: moti bo moti yege

Call: we decree and declare ati bo oo ati yege

Resp: motibo motiyege

Call: e mase bawa wi awa lomoba laafin atibo a o serum

Resp: moti bo mo ti yege

Exit mobile version